Lyrics

LYRICS: Brymo – Temi Ni Temi

brymolawale 20210909 0001 10 - LYRICS: Brymo – Temi Ni Temi

Brymo – Temi Ni Temi Lyrics.

Ife mi dariji mi
Omode n se mi
Afarawe O se temi
Ka daduro ni mo wari
Moti so tele tele ri
Igboro O ma rerin ri
Ijakadi lo mu nise
Karohunwi O bopo sise

images - LYRICS: Brymo – Temi Ni Temi

Bridge
Bi nba fa wa n’ole
Bi nba tule wan’loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere

Chorus
Aba lo aba bo
B’ohun won ko para won oh
Ohun A ni la n nani
Temi Ni Temi

Verse 2
Awelewa forijimi
Mo lakaka kin to de bi
Riro mede O se temi
Nibi lile la n b’okunrin
Ife re sha lo’n duro timi
O dudu, O funfun, O Pupa
Ife re sha lo’n munu tumi
Ninu erun at’ojo at:ilera

Bridge
Bi nba fa wa n’ole
Bi nba tule wan’loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere

Chorus
Aba lo aba bo
B’ohun won ko para won oh
Ohun A ni la n nani
Temi Ni Temi

Outro
Aba lo aba bo
Temi loje lale eni oh
Gbogbo igba ti o ba lo
Mo mo pe o pada wa

DOWNLOAD AUDIO: Brymo – Temi Ni Temi

Mayomikun

I'm Raheem Timothy, A passionate Blogger | Architect | Graphics Designer | Digital Marketer. I love content writing and Music is my Inspiration. Together, We can make DripNaija Great!

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button